Oludari ẹka to n mojuto bi awọn banki ṣe n sẹ iṣẹ wọn, Haruna Mustafa, lo fi ikede naa sita. Ọjọ Iṣẹgun ni CBN fi ikede tuntun sita eyi to fihan pe awọn ọmọ Naijiria ko ...